adesinaabegunde_yo_tit_text.../03/09.txt

1 line
376 B
Plaintext

\v 9 Sùgbọ́n yàgò fún àríyànjiyàn agọ̀ àti ìtàn ìran àti asọ̀ àti ìjà nípa ti òfin. Aláìlérè àti asán ni àwọn nǹkan wọn nì. \v 10 Kọ ẹnikẹ́ni tí ó bá ń fa ìyapa láàrín yín, lẹ́yín ìkìlọ̀ kan tàbí ìkejì, \v 11 kí o sì mọ̀ pé irú ẹni bé è ti yapa ó sì ń sẹ̀ ó sì dá ara rẹ̀ lẹ́bi.