adesinaabegunde_yo_tit_text.../03/08.txt

1 line
290 B
Plaintext

\v 8 Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀. Mo fẹ́ kí ẹ sọ̀rọ̀ ǹǹkan wọ̀nyí pẹ̀lú ìdánilójú, kí àwọn tí ó gba Ọlọ́run gbọ́ pinu lórí isẹ́ rere tí ó fi sí iwájú wọn. Àwọn nǹkan wọ̀nyí dára wọ́n sí se àǹfàní fún ènìyàn gbogbo.