adesinaabegunde_yo_tit_text.../02/14.txt

1 line
198 B
Plaintext

\v 14 Jésù fi ara rẹ̀ fún wa láti rà wá padà kúrò nínú ẹ̀sẹ̀ gbogbo àti láti yà wá sí mímọ́, fún ara re, ènìyàn tí ó yátọ̀ tí ó ní ìtara fún isẹ́ rere.