adesinaabegunde_yo_tit_text.../02/01.txt

1 line
279 B
Plaintext

\c 2 \v 1 Ṣùgbọ́n ìwọ, máa sọ ohun tí ó yẹ sí ìtọ́ni tí ó yè koro. \v 2 Àgbàlagbà okùnrin gbọdọ̀ jẹ́ oní-wọ̀n-tun-wọ̀nsì, ẹni-ọ̀wọ̀, ọlọgbọ́n, ẹni tí ó yẹ̀ koro nínú ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àti ìpamọ́ra.