\v 15 Gbogbo àwọn tí ó wà pèlú mi kíi yín. E kí àwọn tí ó nífẹ̌ wa nínú ìgbàgbọ́. Kí ore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo yín.