adesinaabegunde_yo_tit_text.../03/04.txt

1 line
302 B
Plaintext

\v 4 Sùgbọ́n nígbà tí ìsoore Ọlọ́run Olùgbàla wa àti ìfẹ́ rẹ̀ fún ọmọ ènìyàn farahàn, \v 5 kìí se nípa isẹ́ òdodo tí a se, sùgbọ́n nípa ìfẹ́ rẹ̀ ni ó gbà wá. Ó gbà wá nípa ìwẹ̀nùmọ́ titun àti ìsọdòtun nípa ti Ẹ̀mí Mímọ́.