adesinaabegunde_yo_tit_text.../03/03.txt

1 line
263 B
Plaintext

\v 3 Nítorí àwa pẹ̀lú ti jẹ́ aláì-nírònú àti aláìgbọ́ran nígbà kan rí. A di asáko a sì dì wá ní ìgbèkùn sí afẹ́ ayé àti ìfẹ́kúfẹ̌. À ń gbẹ́ ńnú ibi àti ìlara. A jẹ́ ẹni ìlara a sì kórira ẹnikejì.