adesinaabegunde_yo_tit_text.../02/11.txt

1 line
431 B
Plaintext

\v 11 Nítorí ore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ti farahàn sí gbogbo ènìyàn. \v 12 Ó ń kọ́ wa láti lòdì sí àìwà-bí-Ọlọ́run àti ìfẹ́kúfẹ̌ ayé. Ó ń kọ́ wa láti gbé orí pípé, lí òdodo, àti ní ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsinsìyí \v 13 nígbà tí à ń fojú sọ́nà láti gba ìrètí ìbùkún wa, ìfarahàn ògo Ọlọ́run wa tí ó tóbi àti Olùgbàlà wa Jèsu Kristì.