adesinaabegunde_yo_tit_text.../01/15.txt

1 line
454 B
Plaintext

\v 15 Fún àwọn tí ó mọ́, ohun gbogbo ní ó mọ́. Sùgbọ́n sí àwọn tí a sọ di ẹlẹ́gbǐn àti aláìgbàgbọ́, kò sí ohun tí ó tọ́. Nítorí inú wọn àti ẹ̀rí-ọkàn wọn ni a sọ di ẹ̀gbin. \v 16 Wọ́n jẹ́wọ́ pé wọ́n mọ Ọlọ́run, sùgbọ́n wọ́n sẹ́ ẹ nípa ìse wọn. Wọ́n jẹ́ ẹni-ìríra àti aláìgbọ́ràn. A kò sì fi òùntẹ̀ lù wọ́n fún isẹ́ rere.