adesinaabegunde_yo_tit_text.../01/12.txt

1 line
311 B
Plaintext

\v 12 Ọ̀kan nínú wọn, ọkùnrin ọlọgbọ́n wọn, ó wípé, " Àwọn ará Kritani ń parọ́ nígbàgbogbo, wọ́n jẹ́ ẹranko búburú, ọ̀lẹ alájẹkì." \v 13 Ọ̀rọ̀ yí jẹ́ òtítọ́, nítorínà bá wọn wí gidigidi kí wọ́n le yè koro nínú ìgbàgbọ́. \v 14