adesinaabegunde_yo_tit_text.../01/08.txt

1 line
397 B
Plaintext

\v 8 Dípò, kí ó jẹ́ ẹni tí ó kónimọ́ra, ọ̀rẹ ohun dáradára. Ó gbọdọ̀ jẹ́ ọlọgbọ́n, olódodo, ìwà-bí- Ọlọ́run àti ìkóra ẹni ní ìjánu. \v 9 Kí ó di Ọ̀rọ̀ òtítọ́ tí a kọ́ ọ mu shinshin, kí ó ba lè gba àwọn tí ó kù ní ìyànjú pẹ̀lú ìkọ́ni dáradàra àti pẹ̀lú kí ó bá àwọn tí ó lòdì síi wí.