adesinaabegunde_yo_tit_text.../01/04.txt

1 line
343 B
Plaintext

\v 4 Sí Títù, ọmọ tòotú nínú ìgbàgbọ́ wa. Ore-òfẹ́ àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Krístì Jésù Olùgbàlà wa. \v 5 Nítorí èyí ni mo se fi yín sílẹ̀ ní Crétì, pẹ́ kí ẹ lọ to oun gbogbo tí ó nílò àtúntò àti kí ẹ yan alàgbà ní gbogbo ìlú bí mo se rán yín.