commit 68446560eff6046fc1e5800a5d239b7a2dff2a61 Author: scunningham Date: Tue Jan 12 10:35:47 2021 -0500 Tue Jan 12 2021 10:35:47 GMT-0500 (EST) diff --git a/01/01.txt b/01/01.txt new file mode 100644 index 0000000..34794b0 --- /dev/null +++ b/01/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 1 \v 1 Póólu, ìránsẹ́ Ọlọ́run àti àpóstélì Jésù Krístì, fún ìgbàgbọ́ àwọn ènìyàn Ọlọ́run tí a yàn àti ìmọ̀ òtítọ́ ní ìbámu pẹ̀lú ìwà-mímọ́, \v 2 pẹ̀lú ìgboyà iyè àìnípẹ̀kun tí Ọlọ́run, tí kìí parọ́, ti se ìlérí sáájú ki ayé tó bẹ̀rẹ̀ . \v 3 Ní àkókò tí ó tọ́, ó fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ tí ó fi rán mi hàn pẹ̀lú ìgbàgbọ́ láti jísẹ́. Ó yẹ kí n se èyí nípa àsẹ Ọlọ́run Olùgbàlà wa. \ No newline at end of file diff --git a/01/04.txt b/01/04.txt new file mode 100644 index 0000000..6e3b45b --- /dev/null +++ b/01/04.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 4 Sí Títù, ọmọ tòotú nínú ìgbàgbọ́ wa. Ore-òfẹ́ àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Krístì Jésù Olùgbàlà wa. \v 5 Nítorí èyí ni mo se fi yín sílẹ̀ ní Crétì, pẹ́ kí ẹ lọ to oun gbogbo tí ó nílò àtúntò àti kí ẹ yan alàgbà ní gbogbo ìlú bí mo se rán yín. \ No newline at end of file diff --git a/01/06.txt b/01/06.txt new file mode 100644 index 0000000..6a12e78 --- /dev/null +++ b/01/06.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 6 Alàgbà gbọ́dọ̀ wà ni àìlẹ́bi, ọkọ aláya kan, pẹ̀lú àwọn ọmọ olọ́tìtọ́ tí a kò dá lẹ́bi ìwà búburú tàbí àìlẹ́kọ̌. \v 7 Ó pọn dandan fún alámòjútó náà, gẹ́gẹ́ bí olùsọ́ ilé Ọlọ́run, kó wà láì lẹ́bi. Kò gbọdọ̀ jẹ́ aláriwo tàbí aláìkóra-ẹniní-ìjánu . Ko gbodo yara lati maa binu, ko gbodo mu oti waini pupo, ko gbodo feran wahala, ati ko gbodo je wobia okunrin. \ No newline at end of file diff --git a/01/08.txt b/01/08.txt new file mode 100644 index 0000000..a9a3e7d --- /dev/null +++ b/01/08.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 8 Dípò, kí ó jẹ́ ẹni tí ó kónimọ́ra, ọ̀rẹ ohun dáradára. Ó gbọdọ̀ jẹ́ ọlọgbọ́n, olódodo, ìwà-bí- Ọlọ́run àti ìkóra ẹni ní ìjánu. \v 9 Kí ó di Ọ̀rọ̀ òtítọ́ tí a kọ́ ọ mu shinshin, kí ó ba lè gba àwọn tí ó kù ní ìyànjú pẹ̀lú ìkọ́ni dáradàra àti pẹ̀lú kí ó bá àwọn tí ó lòdì síi wí. \ No newline at end of file diff --git a/01/10.txt b/01/10.txt new file mode 100644 index 0000000..1b71378 --- /dev/null +++ b/01/10.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 10 Nítorí àwọn ènìyàn tí ó ní agídí pọ̀, paapa àwọn ti ìkọlà. Ọ̀rọ̀ wọn já sí asán. Wọn ń tan àwọn ènìyàn wọn sì ń darí wọn ní ọ̀nà tí kò tọ̀. \v 11 Ó pọn dandan láti dá wọn lẹ́kun. Wọ́n ń kọ́ oun tí kò yẹ nítorí èrè àìtọ́ wọ́n sì ń da ilé rú. \ No newline at end of file diff --git a/01/12.txt b/01/12.txt new file mode 100644 index 0000000..e460f3f --- /dev/null +++ b/01/12.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 12 Ọ̀kan nínú wọn, ọkùnrin ọlọgbọ́n wọn, ó wípé, " Àwọn ará Kritani ń parọ́ nígbàgbogbo, wọ́n jẹ́ ẹranko búburú, ọ̀lẹ alájẹkì." \v 13 Ọ̀rọ̀ yí jẹ́ òtítọ́, nítorínà bá wọn wí gidigidi kí wọ́n le yè koro nínú ìgbàgbọ́. \ No newline at end of file diff --git a/01/14.txt b/01/14.txt new file mode 100644 index 0000000..388859e --- /dev/null +++ b/01/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Ẹ máse fi ọkàn sí ẹ̀kọ́ asán ti àwọn Ju tàbi òfin àwọn ènìyàn tí wọ́n yí padà kúrò nínú òtítọ́. \ No newline at end of file diff --git a/01/15.txt b/01/15.txt new file mode 100644 index 0000000..77dde41 --- /dev/null +++ b/01/15.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 15 Fún àwọn tí ó mọ́, ohun gbogbo ní ó mọ́. Sùgbọ́n sí àwọn tí a sọ di ẹlẹ́gbǐn àti aláìgbàgbọ́, kò sí ohun tí ó tọ́. Nítorí inú wọn àti ẹ̀rí-ọkàn wọn ni a sọ di ẹ̀gbin. \v 16 Wọ́n jẹ́wọ́ pé wọ́n mọ Ọlọ́run, sùgbọ́n wọ́n sẹ́ ẹ nípa ìse wọn. Wọ́n jẹ́ ẹni-ìríra àti aláìgbọ́ràn. A kò sì fi òùntẹ̀ lù wọ́n fún isẹ́ rere. \ No newline at end of file diff --git a/01/title.txt b/01/title.txt new file mode 100644 index 0000000..9f4294b --- /dev/null +++ b/01/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kìíní \ No newline at end of file diff --git a/02/01.txt b/02/01.txt new file mode 100644 index 0000000..df983cc --- /dev/null +++ b/02/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 2 \v 1 Ṣùgbọ́n ìwọ, máa sọ ohun tí ó yẹ sí ìtọ́ni tí ó yè koro. \v 2 Àgbàlagbà okùnrin gbọdọ̀ jẹ́ oní-wọ̀n-tun-wọ̀nsì, ẹni-ọ̀wọ̀, ọlọgbọ́n, ẹni tí ó yẹ̀ koro nínú ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àti ìpamọ́ra. \ No newline at end of file diff --git a/02/03.txt b/02/03.txt new file mode 100644 index 0000000..08201fc --- /dev/null +++ b/02/03.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 3 Kí àgbàlagbà obìnrin jẹ́ ẹni ọ̀wọ̀, kí íse ẹni tí ó ń sọ̀rọ̀ ẹni lẹ́yìn. kí wọ́n máa se di ẹrú sí ọtí mímu. kí wọ́n kọ́ oun tí ó dára \v 4 láti lè kọ́ àwọn obìnrin kékeré láti nífẹ̌ ọkọ wọn àti ọmọ wọn ní ọ̀nà tí ó tọ́. \v 5 kí wọ́n kọ́ wọn láti jẹ́ ọlọ́pọlọ pípé, ẹni mímọ́, alámojútó ilé, àti ẹni tí ó ń gbọ́ràn sí ọkọ wọn lẹ́nu. Wọ́n gbọdọ̀ se èyí kí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run má ba à di sísọ̀rọ̀ òdì sí. \ No newline at end of file diff --git a/02/06.txt b/02/06.txt new file mode 100644 index 0000000..979504a --- /dev/null +++ b/02/06.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 6 Ní ọ̀nà kannǎ, gba àwọn okùnrin kékeré níyànjú láti jẹ́ ọlọ́pọlọ-pípé. \v 7 Ní ọ̀nà gbogbo fi ara rẹ hàn ní àpẹẹrẹ isẹ́ rere; àti nígbà tí ìwọ bá ń kọ́ni, fi ìwà òtítọ́ àti àgbà hàn. \v 8 Sọ ọ̀rọ̀ tí ó yè koro àti aláìlẹ́bi, kí ojú le è ti ẹnikẹ́ni tí ó bá lòdì si, nítorí kò ní ohun búburú kan láti sọ nípa wa. \ No newline at end of file diff --git a/02/09.txt b/02/09.txt new file mode 100644 index 0000000..072e5c5 --- /dev/null +++ b/02/09.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 9 Ó yẹ kí ẹrú gbọ́ràn sí ọ̀gá rẹ̀ lẹ́nu nínú ohun gbogbo. Ó yẹ kí wọ́n wù wọ́n dípò báwọn jiyàn. \v 10 Kí wọn kí ó má se ìrẹ́jẹ. Dípò bẹ̌, kí wọn kí ó fi ìgbàgbọ́ rere hàn, tó bè ní gbogbo ọ̀nà kí wọn kí ó le se ẹ̀kọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Olúgbàlà wa tí à ń kọ̀ ní ọ̀sọ́. \ No newline at end of file diff --git a/02/11.txt b/02/11.txt new file mode 100644 index 0000000..705ea84 --- /dev/null +++ b/02/11.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 11 Nítorí ore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ti farahàn sí gbogbo ènìyàn. \v 12 Ó ń kọ́ wa láti lòdì sí àìwà-bí-Ọlọ́run àti ìfẹ́kúfẹ̌ ayé. Ó ń kọ́ wa láti gbé orí pípé, lí òdodo, àti ní ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsinsìyí \v 13 nígbà tí à ń fojú sọ́nà láti gba ìrètí ìbùkún wa, ìfarahàn ògo Ọlọ́run wa tí ó tóbi àti Olùgbàlà wa Jèsu Kristì. \ No newline at end of file diff --git a/02/14.txt b/02/14.txt new file mode 100644 index 0000000..be5d822 --- /dev/null +++ b/02/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Jésù fi ara rẹ̀ fún wa láti rà wá padà kúrò nínú ẹ̀sẹ̀ gbogbo àti láti yà wá sí mímọ́, fún ara re, ènìyàn tí ó yátọ̀ tí ó ní ìtara fún isẹ́ rere. \ No newline at end of file diff --git a/02/15.txt b/02/15.txt new file mode 100644 index 0000000..87cf15c --- /dev/null +++ b/02/15.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 15 Nǹkan wọ̀nyí ni kí ìwọ kí ó máa sọ kí o sì gba ni níyànjú. Máa fi àsẹ gbogbo bá ni wí. Mà se jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kí ó gàn ọ́. \ No newline at end of file diff --git a/02/title.txt b/02/title.txt new file mode 100644 index 0000000..1888b36 --- /dev/null +++ b/02/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí kejì \ No newline at end of file diff --git a/03/01.txt b/03/01.txt new file mode 100644 index 0000000..dd9c8ba --- /dev/null +++ b/03/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 3 \v 1 Rán wọn létí láti máa tẹríba fún àwọn adarí àti àwọn alásẹ, láti gbó ti wọn, àti láti múra sílẹ̀ fún isẹ́ rere gbogbo. \v 2 Rán wọn létí kí wọ́n má se sọ ọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni lẹ́yìn, kí wọ́n yàgò fún ìjà, kí wọ́n jẹ́ kí àwọn ènìyàn ní ìfẹ́ ọkàn wọn, kí wọ́n máa fi ìwà tútù hàn sí gbogbo ènìyàn. \ No newline at end of file diff --git a/03/03.txt b/03/03.txt new file mode 100644 index 0000000..fb2e96f --- /dev/null +++ b/03/03.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 3 Nítorí àwa pẹ̀lú ti jẹ́ aláì-nírònú àti aláìgbọ́ran nígbà kan rí. A di asáko a sì dì wá ní ìgbèkùn sí afẹ́ ayé àti ìfẹ́kúfẹ̌. À ń gbẹ́ ńnú ibi àti ìlara. A jẹ́ ẹni ìlara a sì kórira ẹnikejì. \ No newline at end of file diff --git a/03/04.txt b/03/04.txt new file mode 100644 index 0000000..6c79d5a --- /dev/null +++ b/03/04.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 4 Sùgbọ́n nígbà tí ìsoore Ọlọ́run Olùgbàla wa àti ìfẹ́ rẹ̀ fún ọmọ ènìyàn farahàn, \v 5 kìí se nípa isẹ́ òdodo tí a se, sùgbọ́n nípa ìfẹ́ rẹ̀ ni ó gbà wá. Ó gbà wá nípa ìwẹ̀nùmọ́ titun àti ìsọdòtun nípa ti Ẹ̀mí Mímọ́. \ No newline at end of file diff --git a/03/06.txt b/03/06.txt new file mode 100644 index 0000000..3e6a6f3 --- /dev/null +++ b/03/06.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 6 Ọlọ́run da Ẹ̀mí MÍmọ́ sí wa lórí lọ́pọ̀lọpọ̀ nípasè Olúgbàla wa Jésù Kristì. \v 7 Ó se èyí, nígbà tí a ti dá wa láre nípa ore-ọ̀fẹ́, kí á le jẹ́ ajogún nípasè ìgboyà ayérayé. \ No newline at end of file diff --git a/03/08.txt b/03/08.txt new file mode 100644 index 0000000..1654f7c --- /dev/null +++ b/03/08.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 8 Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀. Mo fẹ́ kí ẹ sọ̀rọ̀ ǹǹkan wọ̀nyí pẹ̀lú ìdánilójú, kí àwọn tí ó gba Ọlọ́run gbọ́ pinu lórí isẹ́ rere tí ó fi sí iwájú wọn. Àwọn nǹkan wọ̀nyí dára wọ́n sí se àǹfàní fún ènìyàn gbogbo. \ No newline at end of file diff --git a/03/09.txt b/03/09.txt new file mode 100644 index 0000000..e7fa290 --- /dev/null +++ b/03/09.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 9 Sùgbọ́n yàgò fún àríyànjiyàn agọ̀ àti ìtàn ìran àti asọ̀ àti ìjà nípa ti òfin. Aláìlérè àti asán ni àwọn nǹkan wọn nì. \v 10 Kọ ẹnikẹ́ni tí ó bá ń fa ìyapa láàrín yín, lẹ́yín ìkìlọ̀ kan tàbí ìkejì, \v 11 kí o sì mọ̀ pé irú ẹni bé è ti yapa ó sì ń sẹ̀ ó sì dá ara rẹ̀ lẹ́bi. \ No newline at end of file diff --git a/03/12.txt b/03/12.txt new file mode 100644 index 0000000..f4997dc --- /dev/null +++ b/03/12.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 12 NÍgbà tí mo bá rán Artemasi tàbí Tikiku sí ọ, yára wá sí ọ̀dọ̀ mini Nikoploisi, níbi tí mo ti pinu láti lo àkókó òtútú mi. \v 13 Yára kí o rán Ṣenasi, amòfin, àti Apollo, nií ọ̀nà tí wọn kò ní se aláìní ohunkóun. \ No newline at end of file diff --git a/03/14.txt b/03/14.txt new file mode 100644 index 0000000..0bfb707 --- /dev/null +++ b/03/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Kí àwọn ènìyàn wá kọ́ láti máa se isẹ́ rere ti ó ń bá àìní pàdé kí wọ́n má baà jẹ́ aláìléso. \ No newline at end of file diff --git a/03/15.txt b/03/15.txt new file mode 100644 index 0000000..586cc56 --- /dev/null +++ b/03/15.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 15 Gbogbo àwọn tí ó wà pèlú mi kíi yín. E kí àwọn tí ó nífẹ̌ wa nínú ìgbàgbọ́. Kí ore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo yín. \ No newline at end of file diff --git a/03/title.txt b/03/title.txt new file mode 100644 index 0000000..ed4a489 --- /dev/null +++ b/03/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kẹta \ No newline at end of file diff --git a/LICENSE.md b/LICENSE.md new file mode 100644 index 0000000..98f733d --- /dev/null +++ b/LICENSE.md @@ -0,0 +1,29 @@ + +# License +## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0) + +This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/. + +### You are free to: + + * **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format + * **Adapt** — remix, transform, and build upon the material + +for any purpose, even commercially. + +The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms. + +### Under the following conditions: + + * **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work. + * **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original. + +**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits. + +### Notices: + +You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation. + +No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material. + +This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/). diff --git a/front/title.txt b/front/title.txt new file mode 100644 index 0000000..af09a62 --- /dev/null +++ b/front/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Títù \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json new file mode 100644 index 0000000..f91bd6b --- /dev/null +++ b/manifest.json @@ -0,0 +1,68 @@ +{ + "package_version": 7, + "format": "usfm", + "generator": { + "name": "ts-desktop", + "build": "5" + }, + "target_language": { + "id": "yo", + "name": "Yorùbá", + "direction": "ltr" + }, + "project": { + "id": "tit", + "name": "Titus" + }, + "type": { + "id": "text", + "name": "Text" + }, + "resource": { + "id": "ulb", + "name": "Unlocked Literal Bible" + }, + "source_translations": [ + { + "language_id": "en", + "resource_id": "ulb", + "checking_level": "3", + "date_modified": "2017-11-29T00:00:00+00:00", + "version": "12" + } + ], + "parent_draft": {}, + "translators": [ + "adegokeaanuoluwapo", + "adegoke aanuoluwapo", + "adesina abegunde" + ], + "finished_chunks": [ + "front-title", + "01-title", + "01-01", + "01-04", + "01-06", + "01-08", + "01-10", + "01-15", + "02-title", + "02-01", + "02-03", + "02-06", + "02-09", + "02-11", + "02-14", + "02-15", + "03-title", + "03-01", + "03-03", + "03-04", + "03-06", + "03-08", + "03-09", + "03-12", + "03-14", + "03-15" + ] +} \ No newline at end of file