adesinaabegunde_yo_php_text.../01/07.txt

1 line
359 B
Plaintext

\v 7 Ó yẹ kí n ní ìmọ̀lára yìí nípa gbogbo yín nítorí mo fi yín sọ́kàn. GBogbo yín ti jẹ́ alábàápín oore-ọ̀fẹ́ pẹ̀lú mi nínú ìgbèkún mi, nínú àwíjàre mi àti nínú ìfìdímúlẹ̀ ìhìnrere. \v 8 Ọlọ́run mọ̀ bí ọkàn mi ṣe ń pòǹgbẹ fún gbogbo yín pẹ̀lú ìkáànú Krístì Jésù.