adesinaabegunde_yo_php_text.../03/15.txt

1 line
270 B
Plaintext

\v 15 Gbogbo àwa tí a ti dàgbà, ẹ jẹ́ kí á ma ronú báyìí; bí o bá sì fi ojú mìráǹ wo ohunkohun, Ọlọ́run yíò fi èyí náà hàn ọ́. \v 16 Ṣùgbọ́n ṣá, ohunkohun tí ọwọ́ wa bá ti bà, ẹ jẹ́ kí á dìí mú ṣinṣin.