adesinaabegunde_yo_php_text.../03/04.txt

1 line
352 B
Plaintext

\v 4 Bẹ́ẹ̀ sì ni, èmi pẹ̀lú le gbékẹ̀lé ẹran ara. Bí ẹnikẹ́ni bá rò pé òun le gbékẹ̀lé ẹran ara, èmi pẹ̀lú le ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ. \v 5 A kọ mí nílà ní ọjọ́ kẹjọ, ojúlówó ọmọ Ísráẹ́lì, láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámẹ́nì, ògidì Hébérù; níti òfin, Farisí ni mí.