adesinaabegunde_yo_php_text.../02/22.txt

1 line
388 B
Plaintext

\v 22 Ṣùgbọ́n ẹ̀yín mọyì rẹ̀, pé bí ọmọ ti ń sin baba, bẹ́ẹ̀ni ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú mi nínú ìhìnrere. \v 23 Nítorí náà mo ń gbèrò láti rán an sí yín ní kété tí mo bá mọ bí ǹkan ṣe ń lọ pẹ̀lú mi. \v 24 Ṣùgbọ́n ọkàn mi balẹ̀ nínú Olúwa pé èmi pàápàá kò ní pẹ́ yọjú sí yín fúnrara mi.