adesinaabegunde_yo_php_text.../02/05.txt

1 line
451 B
Plaintext

\v 5 Ẹ máa ronú gẹ́gẹ́ bí Krístì Jésù ti ronú. \v 6 Bí Ó tilẹ̀ jẹ́ Ọlọ́run, Òun kò rò pé ìbádọ́gba pẹ̀lú Ọlọ́run jẹ́ ohun tí à bá gbéléjú. \v 7 Kàkà bẹ́ẹ̀, Ó da ohun gbogbo sílẹ̀. Ó sì gbé àwọ̀ ẹrú wọ. Ó farahàn ní ìrísí ènìyàn. A sì rí I bíi ènìyàn. \v 8 Ó rẹ ara Rẹ̀ sílẹ̀ Ó sì gbọ́ràn títí dé ojú ikú, àní ikú orí àgbélèbú!