adesinaabegunde_yo_php_text.../01/28.txt

1 line
526 B
Plaintext

\v 28 Ẹ máṣe jẹ́ kí àwọn alátakò yín kí ó da jìnnìjìnnì bò yín bí tií wulẹ̀ kó mọ. Èyí jẹ́ àmì fún wọn fún ìparun wọn, ṣùgbọ́n fún ìgbàlà yín - láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run sì ni èyí. \v 29 Nítorí a ti fi fún un yín, nítorí Krístì, kì í ṣe láti gbà á gbọ́ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí Rẹ̀ pẹ̀lú, \v 30 kí ẹ̀yín kí ó ní ìlàkọjá kan náà tí ẹ rí tí mo ní, tí ẹ sì gbọ́ tí mo ń sọ nísinsìnyí.