adesinaabegunde_yo_php_text.../01/22.txt

1 line
335 B
Plaintext

\v 22 Ṣùgbọ́n bí mo bá wà láàyè, ó túmọ̀ sí iṣẹ́ tó léso fún mi. Síbẹ̀ èwo ni kí n yàn? N kò tilẹ̀ mọ̀. \v 23 Méjéèjì ń ṣe kámikàmìkámi. Ó wù mí kí n kú kí n le wà pẹ̀lú Krístì, èyí tí ó sàn jù, \v 24 síbẹ̀ ó ṣe pàtàkì kí n wà láàyè nítorí tiyín.