adesinaabegunde_yo_php_text.../01/15.txt

1 line
451 B
Plaintext

\v 15 Nítòótọ́ àwọn kan ń kéde Krístì pẹ̀lú owú àti ìlara, àti àwọn míran pẹ̀lú inú-rere. \v 16 Àwọn wọ̀nyí ń ṣe é pẹ̀lú ìfẹ́, wọ́n mọ̀ pé a pè mí kí n wá wíjọ́ nítorí ìhìnrere ni. \v 17 Ṣùgbọ́n àwọn tọ̀hún ń kéde Krístì nínú ìlépa-taraẹni-nìkan ni, kìí ṣe nínú òtítọ́. Wọ́n rò pé àwọn yóò pa mí lára nígbàtí mo wà nínú ìdè.