Wed Oct 23 2019 04:15:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:15:13 +01:00
parent 3e5e5caaeb
commit ae8239591f
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Níparí, ẹ̀yin ará mi, àwọn ohunkóhun yówù tí ó jẹ́ òtítọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó lọ́lá, àwọn ohunkóhun yówù tí ó tọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó mọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó wuni, àwọn ohunkóhun yówù tí ó ní ìròyìn rere, bi ohunkóhun bá pegedé, bi ohunkóhun bá yẹ fún ìyìn, ẹ máa ronú lórí àwọn nǹkan wọ̀nyí. \v 9 àwọn nǹkan tí ẹ ti kọ́ tí ẹ sì ti gbà, tí ẹ ti gbọ́ tí ẹ sì ti rí nínúù mi, ẹ máa
\v 8 Níparí, ẹ̀yin ará mi, àwọn ohunkóhun yówù tí ó jẹ́ òtítọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó lọ́lá, àwọn ohunkóhun yówù tí ó tọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó mọ́, àwọn ohunkóhun yówù tí ó wuni, àwọn ohunkóhun yówù tí ó ní ìròyìn rere, bi ohunkóhun bá pegedé, bi ohunkóhun bá yẹ fún ìyìn, ẹ máa ronú lórí àwọn nǹkan wọ̀nyí. \v 9 àwọn nǹkan tí ẹ ti kọ́ tí ẹ sì ti gbà, tí ẹ ti gbọ́ tí ẹ sì ti rí nínúù mi, ẹ máa ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí, àlàáfíà Ọlọ́run yíó sì wá pẹ̀lú yín.

1
04/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 \v 11 \v 12 \v 13 n