Wed Jul 03 2019 09:11:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-03 09:11:21 +01:00
parent 5af82b07f7
commit 91fc05adea
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 Kìkì pé kí ẹ̀yin kí ó má gbé ìgbé-ayé yín ní ìbámu pẹ̀lú ìhìnrere Krístì, tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bóyá mo wá wò yín tàbí n kò wá, èmi yóò lè máa gbọ́ nípa yín, pé ẹ̀ ń dúró ṣinṣin pẹ̀lú ẹ̀mí kan, ẹ sì ń lépa papọ̀ fún ìgbàgbọ́
\v 25 Pẹ̀lú àrídájú ohun kan yìí, mo mọ̀ pé èmi yóò wà pẹ̀lú yín síi fún ìtẹ̀síwájú yín àti ayọ̀ yín nínú ìgbàgbọ́. \v 26 Kí ẹ̀yin kí ó lè ní ìdí síi láti yangàn nínú Krístì Jésù láti ipasẹ̀ mi nígbàtí mo bá tún tọ̀ yín wá. \v 27 Kìkì pé kí ẹ̀yin kí ó má gbé ìgbé-ayé yín ní ìbámu pẹ̀lú ìhìnrere Krístì, tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bóyá mo wá wò yín tàbí n kò wá, èmi yóò lè máa gbọ́ nípa yín, pé ẹ̀ ń dúró ṣinṣin pẹ̀lú ẹ̀mí kan, ẹ sì ń lépa papọ̀ fún ìgbàgbọ́ ìhìnrere náà pẹ̀lú ọkàn kan.

1
01/28.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 28 Ẹ máṣe jẹ́ kí àwọn al \v 29 \v 30 n