Fri Jun 14 2019 23:00:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-14 23:00:27 +01:00
parent ccede458fb
commit 63b885f0d5
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run mi ní gbogbo ìgbà tí mo bá rántí yín. \v 4 Ní gbogbo ìgbà tí mo bá ń gbàdúrà fún gbogbo yín, tayọ̀tayọ̀ ni mo fi ń gbàá. \v 5 Mo dúpẹ́ fún bí ẹ ti ṣe alábàpiń nínu ìhìnrere náà láti ìbẹ̀rẹ̀ títí di ìsinsìnyí. \v 6 Mo ní ìgboyà ohun kan yí, pé Ẹnití ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rere nínú yín yíò tẹ̀síwájú láti yanjú rẹ̀ títí di ọjọ
\v 3 Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run mi ní gbogbo ìgbà tí mo bá rántí yín. \v 4 Ní gbogbo ìgbà tí mo bá ń gbàdúrà fún gbogbo yín, tayọ̀tayọ̀ ni mo fi ń gbàá. \v 5 Mo dúpẹ́ fún bí ẹ ti ṣe alábàpiń nínu ìhìnrere náà láti ìbẹ̀rẹ̀ títí di ìsinsìnyí. \v 6 Mo ní ìgboyà ohun kan yí, pé Ẹnití ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rere nínú yín yíò tẹ̀síwájú láti yanjú rẹ̀ títí di ọjọ́ Jésù Krístì.