Fri Jul 05 2019 10:21:45 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-05 10:21:45 +01:00
parent 742b8d5277
commit 5364b133a1
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 25 Ṣùgbọ́n mo rò pé ó yẹ kí n rán Ẹ̀páfródítù padà sí yín. Arákùnrin mi ni, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi ni, akẹgbẹ́-ọmọ-ogun ni pẹ̀lú mi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ìráńṣẹ́ yín tí ó ń mójútó àwọn àìní mi. \v 26 Nítorí tí ọkàn rẹ̀ pòrurù gidi gan, ó sì ń jarán láti wà pẹ̀lú yín nítorí tí ẹ gbọ́ pé ara rẹ̀ kò yá. \v 27 Lóòótọ́ ni pé ó ṣe àìsàn dé ojú ikú. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ṣàánú fún un, kì í sì ṣe fún òhun nìkan, ṣùgbọ́n fún èmi náà,
\v 25 Ṣùgbọ́n mo rò pé ó yẹ kí n rán Ẹ̀páfródítù padà sí yín. Arákùnrin mi ni, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ mi ni, akẹgbẹ́-ọmọ-ogun ni pẹ̀lú mi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ìráńṣẹ́ yín tí ó ń mójútó àwọn àìní mi. \v 26 Nítorí tí ọkàn rẹ̀ pòrurù gidi gan, ó sì ń jarán láti wà pẹ̀lú yín nítorí tí ẹ gbọ́ pé ara rẹ̀ kò yá. \v 27 Lóòótọ́ ni pé ó ṣe àìsàn dé ojú ikú. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ṣàánú fún un, kì í sì ṣe fún òhun nìkan, ṣùgbọ́n fún èmi náà, kí ìbànújẹ́ mi má baà peléke síi.

1
02/28.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 28 \v 29 \v 30 m