Thu Jul 04 2019 12:27:58 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-04 12:27:58 +01:00
parent 211d504f7c
commit 4152e1146e
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Máṣe ṣe ohunkóhun nínú ìmọtara-ẹni-nìkan àbi ìgbéraga. Kàkà bẹ́ẹ̀ nínú ìrẹ̀lẹ̀ ka elòmíràn kún ju ara rẹ lọ. \v 4 Kí olúkúlùkù yín máa tán àìní àwọn ẹlòmíràn pẹ̀lú, kí ó má sì ṣe tán ti ara rẹ̀ nìkan.
\v 3 Ẹ máṣe ṣe ohunkóhun nínú ìmọtara-ẹni-nìkan tàbi ìgbéraga. Kàkà bẹ́ẹ̀ nínú ìrẹ̀lẹ̀ ka elòmíràn kún ju ara lọ. \v 4 Kí olúkúlùkù yín máa tán àìní àwọn ẹlòmíràn pẹ̀lú, kí ó má sì ṣe tán ti ara rẹ̀ nìkan.

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Ẹ máa ṣe ohun gbogbo láìsí ìkùnsínú tàbí àríyànjiyàn. \v 15 Ẹ hùwà báyìí kí ẹ̀yin kí o le di aláìléèéri àti olótítọ́, àwọn ọmọ Ọlọ́run tí kò lábàwọ́n. Ẹ hùwà báyìí kí ẹ̀yin kí o le tàn bíi ìmọ́lẹ̀ nínú ayé, láàrin ìran tí kò tọ́ tí iyè wọn sì ti ra. \v 16 Ẹ di ọ̀rọ̀ ìyè mú ṣinṣin kí èmi kí ó le nídìí láti ṣògo lọ́jọ́ Krístì. Nítorí nígbà náà ni èmi yóò mọ̀ pé èmi kò lépa lásán bẹ́ẹ̀ sì ni n kò ṣe làálàá lásán
\v 14 Ẹ máa ṣe ohun gbogbo láìsí ìkùnsínú tàbí àríyànjiyàn. \v 15 Ẹ hùwà báyìí kí ẹ̀yin kí o le di aláìléèéri àti olótítọ́, àwọn ọmọ Ọlọ́run tí kò lábàwọ́n. Ẹ hùwà báyìí kí ẹ̀yin kí o le tàn bíi ìmọ́lẹ̀ nínú ayé, láàrin ìran tí kò tọ́ tí iyè wọn sì ti ra. \v 16 Ẹ di ọ̀rọ̀ ìyè mú ṣinṣin kí èmi kí ó le nídìí láti ṣògo lọ́jọ́ Krístì. Nítorí nígbà náà ni èmi yóò mọ̀ pé èmi kò lépa lásán bẹ́ẹ̀ sì ni n kò ṣe làálàá lásán.

View File

@ -48,6 +48,7 @@
"01-20",
"01-22",
"01-25",
"01-28"
"01-28",
"02-01"
]
}