Wed Oct 23 2019 04:55:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:55:13 +01:00
parent 03925ff0b5
commit 32a888f393
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pà \v 20
\v 18 Mo ti gba gbogbo àwọn nǹkan náà, mo sì ní ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ní ànító. Èpáfródítu ti fi àwọn nǹkan tí ẹ fi rán an jíṣẹ́ fún mi. Wọ́n jẹ́ ọrẹ olóòórùn-dídùn, tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà tí ó sì wu Ọlọ́run. \v 19 Ọlọ́run mi yíò bá gbogbo àìní yín pàdé ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ Rẹ̀ nínú ògo nínú Krístì Jésù. \v 20