Tue Oct 22 2019 22:04:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-22 22:04:36 +01:00
parent d89a9dc763
commit 2508229676
3 changed files with 5 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Níti ìtara, mo gbógun ti ìjọ; níti òdodo lábẹ́ òfin, èmi kò lábàwọ́n. \v 7 Ṣùgbọ́n mo ti ka gbogbo àwọn ohun tí ó jẹ́ èrè fún mí kún àdánù nítorí Krístì.
\v 6 Níti ìtara, mo gbógun ti ìjọ; níti òdodo lábẹ́ òfin, èmi kò lábùkù. \v 7 Ṣùgbọ́n mo ti ka gbogbo àwọn ohun tí ó jẹ́ èrè fún mí kún àdánù nítorí Krístì.

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Kódà mo ka ohun gbogbo kún àdánù nítorí ìmọ̀ Jésù Krístì Olúwa mi níye lórí ju ohun gbogbo lọ. Nítorí Rẹ̀ mo ti da ohun gbogbo sí ààtàn. Mo kà wọ́n sí ẹ̀gbin kí èmi kí ó le fi Krístì ṣèrè jẹ. \v 9 kí á sì lè rí mi nínú Rẹ̀. Èmi kò ní òdodo ti ara mi láti inú òfin. Kàkà bẹ́ẹ̀, òdodo mi jẹ́ èyí tí ó wá láti ipasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Krístì, òdodo ti Ọlọ́run tí ó fìdí múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́. \v 10 Ǹjẹ́ nísinsìyí èmi fẹ́ mọ̀ Ọ́ àti agbára àjíǹde Rẹ̀ àti ìfarakínra àwọn ìjìyà Rẹ̀. Mo fẹ́ kí á yí mi padà sínú ìrísí ikú Rẹ̀, \v 11 kí èmi kí ó le ní ìrírí àjíǹde kúrò láàrin àwọn òkú.
\v 8 Kódà, nísinsìnyí mo ka ohun gbogbo kún àdánù nítorí ìmọ̀ Jésù Krístì Olúwa mi níye lórí ju ohun gbogbo lọ. Nítorí Rẹ̀ mo ti da ohun gbogbo sí ààtàn. Mo kà wọ́n sí ẹ̀gbin kí èmi kí ó le fi Krístì ṣèrè jẹ. \v 9 kí á sì lè rí mi nínú Rẹ̀. Èmi kò ní òdodo ti ara mi láti inú òfin. Kàkà bẹ́ẹ̀, òdodo mi jẹ́ èyí tí ó wá láti ipasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Krístì, òdodo ti Ọlọ́run tí ó fìdí múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́. \v 10 Ǹjẹ́ nísinsìyí èmi fẹ́ mọ̀ Ọ́ àti agbára àjíǹde Rẹ̀ àti ìfarakínra àwọn ìjìyà Rẹ̀. Mo fẹ́ kí á yí mi padà sínú ìrísí ikú Rẹ̀, \v 11 kí èmi kí ó le ní ìrírí àjíǹde kúrò láàrin àwọn òkú.

View File

@ -61,6 +61,8 @@
"02-25",
"02-28",
"03-title",
"03-01"
"03-01",
"03-04",
"03-06"
]
}