Wed Oct 23 2019 04:03:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:03:13 +01:00
parent c0eec7fbae
commit 1d427749fd
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Ẹ máa yọ̀ nínú Olúwa nígbàgbogbo. Lẹ́ẹ̀kansíì màá tún sọ pe, ẹ máa yọ̀. \v 5 Ẹ jẹ́ kí ìwàpẹ̀lẹ́ yín di mímọ̀ fún gbogbo ènìyàn. Olúwa wà nítòsí. \v 6 Ẹ má ṣe káyàsókè nítori ohunkóhun. Kàkà bẹ́ẹ̀, nínú àdúrá áti ẹ̀bẹ̀, pẹ̀lú ọpẹ́, ẹ sọ ẹ̀bẹ̀ yín di mímọ̀ fún Ọlọ̀run, \v 7 àlàáfíà Ọlọ́run tí ó tayọ gbogbo òye yíò sì pa àwọkàn àti èrò yín mọ́.
\v 4 Ẹ máa yọ̀ nínú Olúwa nígbàgbogbo. Lẹ́ẹ̀kansíì màá tún sọ pe, ẹ máa yọ̀. \v 5 Ẹ jẹ́ kí ìwàpẹ̀lẹ́ yín di mímọ̀ fún gbogbo ènìyàn. Olúwa wà nítòsí. \v 6 Ẹ má ṣe káyàsókè nítori ohunkóhun. Kàkà bẹ́ẹ̀, nínú àdúrá áti ẹ̀bẹ̀, pẹ̀lú ọpẹ́, ẹ sọ ẹ̀bẹ̀ yín di mímọ̀ fún Ọlọ̀run, \v 7 àlàáfíà Ọlọ́run tí ó tayọ gbogbo òye yíò sì pa àwọn ọkàn àti àwọn èrò yín mọ́ nínú Krístì Jésù.

1
04/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Níparí, ẹ̀yin ará mi, \v 9