Wed Oct 23 2019 04:29:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:29:13 +01:00
parent 789ebbe9ba
commit 177e05bd29
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Mo yọ̀ gidigidi nínú Olúwa nítorí nísinsìnyí, lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, ẹ ti sọ àníyán yín fún mi dọ̀tun. Lóòótọ́ ni ọrọ mí ti ká yín làra tẹ́lẹ, ṣùgbọ́n ẹ kò ní àǹfàní láti ṣe ìrànlọ́wọ́. \v 11 Èmi kò sọ èyí nítorí pé mo ṣe aláìní. Nítorí mo ti kọ́ láti ní ìtẹ́lọ́rùn nínu ipòkípò tí mo bá wà. \v 12 Mo mọ ohun tí ó pè fún láti ṣe àìní, bẹ́ẹ̀ sì ni mo mọ ohun tí ó pè fún láti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. \v 13
\v 10 Mo yọ̀ gidigidi nínú Olúwa nítorí nísinsìnyí, lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, ẹ ti sọ àníyán yín fún mi dọ̀tun. Lóòótọ́ ni ọrọ mí ti ká yín làra tẹ́lẹ, ṣùgbọ́n ẹ kò ní àǹfàní láti ṣe ìrànlọ́wọ́. \v 11 Èmi kò sọ èyí nítorí pé mo ṣe aláìní. Nítorí mo ti kọ́ láti ní ìtẹ́lọ́rùn nínu ipòkípò tí mo bá wà. \v 12 Mo mọ ohun tí ó pè fún láti ṣe àìní, bẹ́ẹ̀ sì ni mo mọ ohun tí ó pè fún láti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. Ní gbogbo ọ̀nà àti nínú ohun gbogbo mo ti kọ́ bí a ṣe ń jẹ àjẹyó àti bi \v 13