adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/28.txt

1 line
272 B
Plaintext

\v 28 Loto ni mo wi fun yin, gbogbo ese awon omo eniyan li o ni idari ji ati awon oro odi ti won so jade, \v 29 sugbon enikeni ti o ba soro odi tako emi mimo ki yi o ri idariji gba lailai sugbon o jebi ese ayeraye \v 30 Jesu so nkan won nitoripe won so pe "o ni emi aimo"