1 line
407 B
Plaintext
1 line
407 B
Plaintext
\v 7 Lẹyin naa Jésù pẹlu awọn ọmọ ẹyin rẹ si lọ si oju odo Galili, ọ̀pọ̀lọpọ̀ awọn eniyan si tele wọn lati Galili ati lati Judia. \v 8 Lati Jerusalemu ati lati ilẹ̀ awọn ará Edomu ati lati ẹ̀yìn odò Jodani wa ati àgbègbè awọn ará Tireni oun Sidoni wa. Nigba ti wọn si gbọ awọn ohun àrà ti a n ti ọwọ rẹ se ọpọ awọn ènìyàn tọọ wa. |