adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/45.txt

1 line
438 B
Plaintext

\v 45 Nígbàtí Pílátù gbọ́ láti ọ̀dọ ọ̀gágun-ọgọ̀rún pé Jésù ti kú, ó yọ̀nda ara rẹ̀ fún Jósẹ́fù \v 46 Jóséfù ti ra asọ. Ó gbe sọ̀kalẹ̀ láti orí àgbélèbú, ó tẹ́ẹ sí inú asọ, ó sì tẹ sí inú ibojì tí a gbẹ́ nínú àpáta. Nígbànáà, ó yí òkúta sí ẹnu ọ̀nà ibojì náà \v 47 Maria Magdaleni àti Maria ìya Jósè rí ibi tí a sin Jésù sí.