adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/33.txt

1 line
447 B
Plaintext

\v 33 Nígbàtí ó di wákàtí kẹfà ọjọ̀, òkùnkùn bo gbogbo ilẹ̀ títí di wákàtí kẹẹ̀sán \v 34 Ní ìgbà tí ó di wákàtí kẹẹ̀sán, Jésù pariwo ní ohùn rara, "Eloi, Eloi, lama sabachthani?" èyí tí ó túmọ̀ sí "Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kílódé tí ìwọ́ fi kọ̀ mí sílẹ̀?" \v 35 Àwọn tí ó dúró gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, wọ́n sì wípé, "wòó, óún pe Èlíjà"