adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/31.txt

1 line
452 B
Plaintext

\v 31 Bàkanáà ni àwọn olórí àlàfáà ńse ẹlẹ́yà rẹ̀ láàrín ara wọn, pẹ̀lú àwọn akọ̀wé, wọ́n sì wípé, "Ó gba àwọn míràn là sùgbọ́n kò lè gba ara rẹ̀. \v 32 Jẹ́kí Krístì náà, Ọba Ísrẹ́ẹ́lì náà, sọ̀kalẹ̀ nísisìyí láti orí àgbélèbú, kí àwá lè ríi, kí à sì gbàgbọ́," àwọn tí a kàn mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú rẹ̀ náà sì kẹ́gàn rẹ̀.