adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/16.txt

1 line
363 B
Plaintext

\v 16 Àwọn ọmọ ogun sì múu wọ inú ilé ẹjọ (èyí tí ńse olú ilé-iṣẹ́ ìjọba), wọ́n sì pe gbogbo àwọn ọmọ ogun ìyókù \v 17 Wọ́n fi asọ ìgúnwà elése àlùkò wọ̀ọ́, wọ́n sì hun adé ẹ̀gún, wọ́n sì fi dée ní orí \v 18 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí júbà rẹ̀ pé "Ìbà o, Ọba àwọn Júù!"