adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/14.txt

1 line
346 B
Plaintext

\v 14 Pílátù sì wí fún wọn, "Kíni àìda tó se?" Sùgbọ́n wọ́n tún pariwo sókè síi, "Kàn-án mọ́ àgbélèbú." \v 15 Pílátù fẹ́ tẹ́ àwọn èrò náà lọ́rùn, nítorínà, ó fi Bárábà sílẹ̀ fún wọn. Ósì naa Jésù, lẹ́yìn náà ó fi lé wọn lọ́wọ́ láti kàán mọ́ àgbélèbú.