adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/04.txt

1 line
204 B
Plaintext

\v 4 Pílátù tún bií léèrè, "Ìwọ kò ní ìdáhùn ni? Wo iye àwọn ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn ọ́!" \v 5 Sùgbọ́n Jésù kò dá Pílátù lóhùn mọ́, èyí sì yàá ní ẹnu.