\v 12 Pílátù sì tún dá wọn lóhùn, "kíni kí èmi se fún Ọba àwọn Júù?" \v 13 wọn sì tún pariwo, "Kàán mọ́ àgbélèbú"