adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/01.txt

1 line
383 B
Plaintext

\c 15 \v 1 Ní àárọ̀ kùtùkùtù, àwọn olórí àlùfa pẹ̀lú àwọn àgbàgbà àti akọ̀wé àti gbogbo ìgbìmọ̀ àwọn Júù. Wọ́n so Jésù, wọn sì múu lọ. Wọ́n fi lé Pílátù lọ́wó. \v 2 Pílátù biì, "Sé ìwọ ni ọba àwọn Júù?" Ó dáalóhùn, "Ìwọ́ wí." \v 3 Àwọn olórí àlùfáà nfi ẹ̀sùn púpọ̀ kan Jésù.