adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/06.txt

1 line
414 B
Plaintext

\v 6 Níssisìyí, ni àsìkò wèje-wẹ̀mu, Pílátù máa nfi ẹlẹ́wọ̀n sílẹ̀, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá fẹ́. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tíó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀ ni ọkùnrin tí à npe ni Baraba wà. \v 8 Èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bèrè pé kó se fun won, oun to tin se tele.