adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/42.txt

1 line
408 B
Plaintext

\v 42 Nígbàtí alẹ́ dé, nítorípé ó jẹ́ ọjọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún Sábátì \v 43 Josefu ará Arimatia wá síbẹ̀. Ó jẹ́ ènìyàn pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ tón dúró de ìjọba Ọlọ́run. Ólọ sí ọ̀dọ Pilatu pẹ̀lù ìgboyà láti bèrè fún ara Jésù. \v 44 Ẹnú ya Pílátù pé Jésù ti kú; ó pe ògágun-ọgọ̀rún láti bií bóyá Jésù ti kú.