adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/33.txt

1 line
442 B
Plaintext

\v 33 Nígbàtí ó di wákàtí kẹfà ọjọ̀, òkùnkùn bo gbogbo ilẹ̀ títí di wákàtí kẹẹ̀sán \v 34 Ní ìgbà tí ó di wákàtí kẹẹ̀sán, Jésù pariwo ní ohùn rara, "Eloi, Eloi, lama sabachthani?" èyí tíó tún mọ̀ sí "Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kílódé tí ìwọ́ kọ̀ mí sí lẹ̀?" \v 35 Àwọn tíó dúró gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, wọ́n sì wípé, "wòó, óún pe Elija"