adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/31.txt

1 line
416 B
Plaintext

\v 31 Bàkanáà ni àwọn olórí àlàfáà se ẹlẹ́yà rẹ̀ láàrín ara wọn, pẹ̀lú àwọn akọ̀wé, wọ́n sì wípé, "Ó gba àwọn míràn sùgbọ́n kò lè gba ara rẹ̀. \v 32 Jẹ́kí Krístì náà, ọ̀ba Isreli náà, sọ̀kalẹ̀ nísisìyí, kí àwá lè ríi, kí à sì gbà á gbọ́," àwọn tí a kàn mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú rẹ̀ náà sì kẹ́gàn rẹ̀.