adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/29.txt

1 line
231 B
Plaintext

\v 29 Àwọn tón kọjá lọ búu, wọ́n mi orí wọn, wọ́nsì wípé, "áha! ìwọ́ tó fẹ́ wó tẹ́mpílì, kóosì tún kọ láàrin ọjọ́ mẹta, \v 30 gba ara rẹ là kosì sọ̀kalẹ̀ láti orí igi!"