adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/25.txt

1 line
307 B
Plaintext

\v 25 Ní wákàtí kẹẹ̀ta ọjọ́ ni wọ́n kàán mọ́ àgbélèbú \v 26 Wọ́n kọ ẹ̀sùn rẹ̀ sí orí pátákó kan pé, "èyí ni ọba àwọn júù." \v 27 Wọ̀n kàán mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú olè mèjí, ìkan ní ọwọ́ ọ̀tún àti ìkan ní ọwọ́ òsì \v 28