adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/22.txt

1 line
320 B
Plaintext

\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ ibi tí à npè ní Golgota (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ njé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjía, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón kàán mọ́ àgbélèbú, wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.