adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/16.txt

1 line
313 B
Plaintext

\v 16 Àwọn ọmọ ogun sì múu wọ inú ilé ẹjọ, wọ́nsì pe gbogbo àwọn ọmọ ogun ìyókù \v 17 Wọ́n fi asọ ìgúnwà elése àlùkò wọ̀ọ́, wọ́nsì hun adé ẹ̀gún, wọ́nsì fi dée ní orí \v 18 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí júbà rẹ̀ pé "Ìbà o, Ọba àwọn Júù!"