\v 25 Ni wakati keeta ojo ni won kan mo agbelebu \v 26 Won ko esun re si ori patako kan pe, "eyi ni oba awon ju." \v 27 Won kan mo agbelebu `pelu ole meji, ikan ni owo otun ati ikan ni owo osi \v 28