adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/16.txt

1 line
199 B
Plaintext

\v 16 Awon eso si mu wo inu ile ejo, wonsi pe gbogbo awon eso iyoku \v 17 Won fi aso igunwa elese aluko wo, wonsi hun ade egun, wonsi fi de ni ori \v 18 Won bere si juba re pe "Iba o, Oba awon Jew!"